Àṣàrò 112: Ìfẹ́ sí Ọlọ́run Ń Mú Ìfẹ́-ọkàn Wa fún Ọlọ́run Pọ̀ Sí I
Nígbà tí o bá fẹ́ràn Ọlọ́run, tí o sì ń yọ̀ nínú ìfẹ́ yẹn, ìfẹ́-ọkàn rẹ fún Ọlọ́run yóò pọ̀ sí i. Bí o ṣe túbọ̀ mọ̀ Ọ́n, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò túbọ̀ fẹ́ mọ̀ Ọ́n; bí o sì ṣe túbọ̀ fẹ́ mọ̀ Ọ́n, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò túbọ̀ mọ̀ Ọ́n. Bákan náà, bí o ṣe túbọ̀ fẹ́ràn Rẹ, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò túbọ̀ fẹ́ láti fẹ́ràn Rẹ…
