Àṣàrò 122: Bí O Bá Lè Yàn
Bí o bá lè yan láàárín gbogbo ọrọ̀ ayé àti àjọṣe tímọ́tímọ́ tí ó kún fún ìfẹ́ pẹ̀lú Jésù, èwo ni ìwọ yóò yàn? Má ṣe yára dáhùn ìbéèrè náà. A lè mọ̀ pé yíyan Jésù ni ìdáhùn tí ó tọ́, ṣùgbọ́n ṣé ìwọ yóò yàn Á? Fojú inú wo agbára àti “òmìnira” ayé tí o…
