Àṣàrò 161: Ìfẹ́ Àrà Ọ̀tọ̀ Tí A Fún Ọ
Nígbà tí a bá ń ṣàṣàrò lórí ìfẹ́ àti Àánú Ọlọ́run, a lè ní ìtẹ̀sí láti wo ìfẹ́ Rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ohun tí ó kan gbogbo ènìyàn lápapọ̀, bí ẹni pé ó jẹ́ ohun tí a pín dọ́gba fún gbogbo ènìyàn lọ́nà kan náà. Ṣùgbọ́n ìfẹ́ Ọlọ́run sí ọ ju ẹ̀bùn tí a fún gbogbo ènìyàn lápapọ̀ lọ fíofío. Ó jẹ́…